Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
July 15, 2011
Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
August 29, 2011–September 4, 2011
Jèhófà Ń Fìfẹ́ Tọ́ Wa Sọ́nà, Ṣé Wàá Tẹ̀ Lé Ìtọ́sọ́nà Rẹ̀?
OJÚ ÌWÉ 10
ÀWỌN ORIN TÍ A Ó KỌ: 26, 3
September 5-11, 2011
Ṣé Wàá Gbọ́ Ìkìlọ̀ Tó Ṣe Kedere Tí Jèhófà Ń Fún Wa?
OJÚ ÌWÉ 15
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 65, 52
September 12-18, 2011
OJÚ ÌWÉ 24
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 19, 27
September 19-25, 2011
OJÚ ÌWÉ 28
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 134, 24
Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 1, 2 OJÚ ÌWÉ 10 sí 19
Nítorí pé Jèhófà nífẹ̀ẹ́ wa, ó máa ń kìlọ̀ fún wa nípa àwọn ewu tó lè mú ká yà kúrò lójú ọ̀nà tó lọ sí ìyè àìnípẹ̀kun. Nínú àwọn àpilẹ̀kọ méjì yìí, a jíròrò ewu mẹ́fà tá a gbọ́dọ̀ ṣọ́ra fún àti bó ṣe yẹ ká ṣọ́ra fún wọn.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 3, 4 OJÚ ÌWÉ 24 sí 32
Bíbélì sọ pé lẹ́yìn tí Jèhófà dá èèyàn, Ó “sinmi” ní ọjọ́ keje. (Héb. 4:4) Àpilẹ̀kọ kẹta tó wà fún ìkẹ́kọ̀ọ́ máa ṣàlàyé ìdí tí Ọlọ́run fi sinmi ní ọjọ́ keje àti ọ̀nà tí ìsinmi rẹ̀ gbà kàn wá. Nínú àpilẹ̀kọ kẹrin tó wà fún ìkẹ́kọ̀ọ́, a máa rí díẹ̀ lára ọ̀nà tá a lè gbà fi hàn pé a ti wọnú ìsinmi Jèhófà.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
3 Ilé Ìṣọ́ Tá A Fi Èdè Gẹ̀ẹ́sì Tó Rọrùn Kọ
4 Ilé Ẹjọ́ Dá Àwọn Èèyàn Jèhófà Láre!
20 Mo Bẹ̀rù Ikú, Àmọ́ Ìyè “Lọ́pọ̀ Yanturu” Ni Mò Ń Retí Báyìí