Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ 2011
Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ 2011
Ó ń tọ́ka sí Ilé Ìṣọ́ tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
A Jẹ́ “Olùgbé fún Ìgbà Díẹ̀” Nínú Ayé Búburú, 11/15
Bá A Ṣe Lè Fi Ọwọ́ Pàtàkì Mú Iṣẹ́ Ìsìn Wa sí Jèhófà, 4/15
Bọ̀wọ̀ fún Ìgbéyàwó Tó Jẹ́ Ẹ̀bùn Ọlọ́run, 1/15
“Èso Ti Ẹ̀mí” Ń Fi Ògo fún Ọlọ́run, 4/15
Ẹ Fi Ìfaradà Sá Eré Ìje Náà, 9/15
Ẹ Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà bí Òpin Ti Ń Sún Mọ́lé, 3/15
Ẹ Kọ́ Àwọn Míì Kí Wọ́n Lè Tóótun fún Àǹfààní Iṣẹ́ Ìsìn, 11/15
Ẹ Máa Lépa Àlàáfíà, 8/15
Ẹ Máa Rìn ní Ìbámu Pẹ̀lú Ẹ̀mí Kẹ́ Ẹ Lè Jogún Ìyè àti Àlàáfíà, 11/15
Ẹ Máa Ṣe Àwọn Ìpinnu Tó Máa Gbé Orúkọ Ọlọ́run Ga, 4/15
“Ẹ Máa Ṣe Olùṣọ́ Àgùntàn Agbo Ọlọ́run Tí Ń Bẹ Lábẹ́ Àbójútó Yín,” 6/15
Ẹ̀mí Mímọ́ Ń Fún Wa Lágbára Ká Lè Borí Àdánwò Èyíkéyìí, 1/15
Ẹ̀mí Mímọ́ Ń Fún Wa Lágbára Ká Lè Kojú Ìdẹwò Ká sì Borí Ìrẹ̀wẹ̀sì, 1/15
Ẹ̀mí Mímọ́ Ni Ọlọ́run Lò Nígbà Ìṣẹ̀dá, 2/15
Ẹ̀mí Ọlọ́run Darí Àwọn Kristẹni ní Ọ̀rúndún Kìíní Ó sì Ń Darí Àwa Náà Lónìí, 12/15
Ẹ̀mí Ọlọ́run Darí Àwọn Olóòótọ́ Ayé Ìgbàanì, 12/15
Ẹ̀mí Ọlọ́run Ni Kó O Gbà, Má Ṣe Gba Ẹ̀mí Ayé, 3/15
“Ẹ Ní Ẹ̀mí Ìkanisí fún Àwọn Tí Ń Ṣiṣẹ́ Kára Láàárín Yín,” 6/15
Ẹ Ran Àwọn Ọkùnrin Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Tẹ̀ Síwájú Nípa Tẹ̀mí, 11/15
Ẹ Sáré . . . Kí Ọwọ́ Yín Lè Tẹ̀ Ẹ́,” 9/15
Ẹ Wà Lójúfò Bíi Ti Jeremáyà, 3/15
Ẹ Wà ní Ìmúratán! 3/15
Ẹ̀yin Ìdílé Kristẹni—“Ẹ Wà Lójúfò,” 5/15
Ẹ̀yin Ìdílé Kristẹni—“Ẹ Wà Ní Ìmúratán,” 5/15
Fi Gbogbo Ọkàn Rẹ Nífẹ̀ẹ́ Òdodo, 2/15
Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà, “Ọlọ́run Ìtùnú Gbogbo,” 10/15
Ìgbọ́kànlé Kíkún Nínú Jèhófà Ń Mú Ká Ní Ìgboyà, 5/15
Ìhìn Rere Tó Yẹ Kí Gbogbo Èèyàn Gbọ́, 6/15
‘Ìjìnlẹ̀ Ọgbọ́n Ọlọ́run Mà Pọ̀ O!’ (Ro 11), 5/15
Ìmọ̀ràn Ọlọgbọ́n Fáwọn Tí Kò Ṣègbéyàwó Àtàwọn Tó Ṣègbéyàwó, 10/15
Jèhófà Ń Fìfẹ́ Tọ́ Wa Sọ́nà, Ṣé Wàá Tẹ̀ Lé Ìtọ́sọ́nà Rẹ̀? 7/15
Jèhófà Ni Ìpín Mi, 9/15
Jèhófà, “Ọlọ́run Tí Ń Fúnni Ní Àlàáfíà,” 8/15
Kí Ni Ìsinmi Ọlọ́run? 7/15
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Jẹ́ Kí Ẹ̀mí Ọlọ́run Máa Darí Wa? 12/15
Lo Ẹ̀bùn Wíwà Láìní Ọkọ Tàbí Aya Lọ́nà Tó Dára Jù Lọ, 1/15
‘Má Ṣe Gbára Lé Òye Tìrẹ,’ 11/15
Ǹjẹ́ O Kórìíra Ìwà Àìlófin? 2/15
Ǹjẹ́ Ò Ń Fi Jèhófà Ṣe Ìpín Rẹ? 9/15
Ọlọ́run Dámọ̀ràn Ìfẹ́ Rẹ̀ fún Wa, 6/15
Rírí Ìtẹ́wọ́gbà Ọlọ́run Ló Máa Mú Ká Jogún Ìyè Àìnípẹ̀kun, 2/15
“Sá Di Orúkọ Jèhófà,” 1/15
Ṣé Àpẹẹrẹ Rere Ló Jẹ́ fún Ẹ àbí Ìkìlọ̀? 12/15
Ṣé Eré Ìtura Tó O Yàn Máa Ṣe Ẹ́ Láǹfààní? 10/15
Ṣé Jèhófà Mọ̀ Ẹ́? 9/15
Ṣé Ò Ń Jẹ́ Kí Ẹ̀mí Ọlọ́run Máa Darí Rẹ? 4/15
Ṣé O Ti Wọnú Ìsinmi Ọlọ́run? 7/15
Ṣé Wàá Gbọ́ Ìkìlọ̀ Tó Ṣe Kedere Tí Jèhófà Ń Fún Wa? 7/15
Ta Ló Ṣe Pàtàkì Jù Lọ ní Ìgbésí Ayé Rẹ? 5/15
“Tu Gbogbo Àwọn Tí Ń Ṣọ̀fọ̀ Nínú,” 10/15
Wọ́n Retí Mèsáyà, 8/15
Wọ́n Rí Mèsáyà! 8/15
ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
“Àǹfààní Ìfúnni Onínúrere” (ọrẹ), 11/15
Àwọn Àpéjọ Àgbègbè “Kí Ìjọba Ọlọ́run Dé!” 6/1
Àwọn Àpéjọ Àgbègbè Nílẹ̀ Rọ́ṣíà, 3/1
Àwọn Ìsọfúnni Tó Máa Ń Wà Nínú Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn Wa Ọdọọdún, 8/15
Ayẹyẹ Ìkẹ́kọ̀ọ́yege Ilé Ẹ̀kọ́ Gílíádì, 2/1, 8/1
Gbèjà Orúkọ Rere (Rọ́ṣíà), 5/1
Ìdí fún Ayọ̀ Yíyọ̀ (ètò), 3/15
Ilé Ẹjọ́ Dá Àwọn Èèyàn Jèhófà Láre! (Rọ́ṣíà), 7/15
Ilé Ìṣọ́ Tá A Fi Èdè Gẹ̀ẹ́sì Tó Rọrùn Kọ (ìwé ìròyìn), 7/15
Ìpàdé Ọdọọdún, 8/15
Lẹ́tà Láti . . . , 3/1, 6/1, 9/1, 12/1
Ṣé Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Gba Ìtọ́jú Lọ́dọ̀ Àwọn Dókítà? 2/1
“Wọ́n Kọ̀ Jálẹ̀, Ó Yẹ Ká Bọ̀wọ̀ fún Wọn” (Ìjọba Násì, Orílẹ̀-èdè Jámánì), 10/1
BÍBÉLÌ
Abala Àwọn Ọ̀dọ́, 1/1, 3/1, 5/1, 7/1, 9/1, 11/1
Àwọn Wo Lára Àwọn Tó Kọ Ìwé Mímọ́ Kristẹni Lédè Gíríìkì Ló Wà ní Pẹ́ńtíkọ́sì Ọdún 33 Sànmánì Kristẹni? 12/1
Ìgbà Tí Wọ́n Kọ Ọ́, 6/1
Ìsapá Zamora Láti Túmọ̀ Ìwé Mímọ́ Lọ́nà Tó Péye, 12/1
Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà, 2/1, 4/1, 5/1, 7/1, 8/1, 10/1, 11/1
Mẹ́fà Nínú Àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì Tó Ń Ṣẹ Lójú Wa, 5/1
Olivétan—‘Onírẹ̀lẹ̀ Tó Túmọ̀’ Bíbélì, 9/1
Ṣé Kíkẹ́kọ̀ọ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Máa Ń Gbádùn Mọ́ Ẹ? 5/15
Wákàtí Ọjọ́, 5/1
ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI
Bí O Ṣe Lè Yan Ọ̀rẹ́ Rere? 12/1
Bíi Ti Fíníhásì Bó O Bá Dojú Kọ Àwọn Ipò Tó Nira, 9/15
Ẹ Jẹ́ Ká Jọ Máa Yọ̀! 10/15
Ẹ Má Ṣe Fi Èrò Èké Tan Ara Yín Jẹ, 3/15
Fòye Mọ Ẹ̀rí Tó Fi Hàn Pé Ọlọ́run Ń Tọ́ Wa Sọ́nà, 4/15
Ìbéèrè Tó Dá Lórí Bíbélì, Kí Ló Yẹ Kí N Ṣe Tí Mo Bá Nílò Ìmọ̀ràn Nípa Ìṣòro Kan? 10/15
“Ìgbà Nínífẹ̀ẹ́ àti Ìgbà Kíkórìíra,” 12/1
‘Ìgbọràn Sàn Ju Ẹbọ Lọ,’ 2/15
Ìjọsìn Ìdílé, 8/15
Íńtánẹ́ẹ̀tì, 8/15
Ipa Tí Ọmọ Lè Ní Lórí Àjọṣe Ọkọ àti Aya, 5/1
Ìsapá Náà Tó Bẹ́ẹ̀ Ó Jù Bẹ́ẹ̀ Lọ! (Ìjọsìn Ìdílé), 2/15
Kí Làwọn Bàbá Lè Ṣe Tí Àjọṣe Wọn Pẹ̀lú Ọmọkùnrin Wọn Kò Fi Ní Bà Jẹ́? 11/1
Kí Ló Lè Mú Kí Ìdílé Rẹ Jẹ́ Aláyọ̀? 10/1
Kí Ló Lè Mú Kí Ìgbéyàwó Wà Pẹ́ Títí? 2/1
Kọ́ Àwọn Ọmọ Láti Máa Bọ̀wọ̀ Fúnni, 2/15
Kọ́ Àwọn Ọmọ ní Ohun Tó Tọ́ Nípa Ìbálòpọ̀, 2/1
Kọ́ Ọmọ Rẹ, 2/1, 4/1, 6/1, 8/1, 10/1, 12/1
Má Ṣe Jẹ́ Kí Àìlera Ba Ayọ̀ Rẹ Jẹ́, 12/15
Má Ṣe Kọ Àwọn Tẹ́ Ẹ Jọ Jẹ́ Onígbàgbọ́ Sílẹ̀ Láé, 3/15
“Máa Bá A Nìṣó ní Ṣíṣọ́nà” 10/15
Máa Bọ̀wọ̀ fún Ọkọ Tàbí Aya Rẹ, 8/1
Máa Ṣe Àṣàrò Lórí Ohun tí Jèhófà Ti Ṣe fún Ẹ, 1/15
Mọyì Àwọn Ìbùkún Tó O Ní? 2/15
“Mú Kí Ọ̀nà Rẹ Yọrí sí Rere,” 6/15
Olóòótọ́ Nínú Ayé Aláìṣòótọ́, 4/15
Owó Orí, 9/1
Ṣé Ó Yẹ Kí Òbí Kọ́ Àwọn Ọmọ Nípa Ìbálòpọ̀? 11/1
Ṣó Yẹ Kí Àwọn Ọmọdé Ṣe Ìrìbọmi? 6/15
Tọkọtaya, Ẹ Kọ́ Bí Ẹ Ṣe Máa Jẹ́ Ẹni Tẹ̀mí, 11/1
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
“Alábòójútó Rere àti Ọ̀rẹ́ Wa Ọ̀wọ́n” (J. Barr), 5/15
“Aláìlera Ni Mí Báyìí, àmọ́ Mi Ò Ní Wà Bẹ́ẹ̀ Títí Láé!” (S. van der Monde), 11/15
Bí Ọmọbìnrin Jẹ́fútà (J. Soans), 12/1
Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà Ń Fún Mi Láyọ̀ (F. Rusk), 10/15
Kíka Bíbélì Lójoojúmọ́ Ti Fún Mi Lókun (M. Leroy), 9/15
Mo Bẹ̀rù Ikú, àmọ́ Ìyè “Lọ́pọ̀ Yanturu” Ni Mò Ń Retí Báyìí (P. Gatti), 7/15
Mo Dúpẹ́ Pé Àdánwò Kò Mú Kí N Dẹ́kun Láti Máa Sin Jèhófà (M. de Jonge-van den Heuvel), 1/15
Mo Fẹ́ràn Ìrìn-Àjò àti Eré Ìfarapitú (Z. Dimitrova), 6/1
Mo Ti Jàǹfààní Látinú Àwọn Ìyípadà Tí Mo Ṣe (J. Thompson), 12/15
Mo Ti Rí Ọ̀pọ̀ Ohun Rere (A. Bonno), 4/15
JÈHÓFÀ
Àwọn Òfin Tó Ń Darí Àwọn Nǹkan Tó Wà Lójú Ọ̀run, 7/1
Irọ́ Márùn-ún Táwọn Èèyàn Ń Pa Mọ́ Ọlọ́run, 10/1
Kí Ló Yẹ Kí Àwọn Ọmọdé Kọ́? 8/1
Kí Ni Ọlọ́run Ní Lọ́kàn fún Ilẹ̀ Ayé? 4/1
Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Fàyè Gba Ìwà Ibi àti Ìjìyà? 5/1
Kí Nìdí Tó Fi Jẹ́ Pé Àparò Ni Ọlọ́run Fi Bọ́ Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì? 9/1
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Lọ́dọ̀ Ọlọ́run? 1/1
Ní Ibì Kan Tó Ń Gbé? 8/1
Ǹjẹ́ Ọlọ́run Bìkítà Nípa Rẹ? 1/1
Ǹjẹ́ Ọlọ́run Mọ̀ Pé Ádámù àti Éfà Máa Dẹ́ṣẹ̀? 1/1
Ǹjẹ́ Ọlọ́run Ń Gbé Ẹ̀yà Ìran Kan Ga Ju Òmíràn Lọ? 7/1
Ǹjẹ́ Ọlọ́run Ní Ètò Kan Tó Gbé Kalẹ̀? 6/1
Òfin Ọlọ́run Ń Ṣe Wá Láǹfààní, 1/1
Orúkọ Níbi Àfonífojì (Orílẹ̀-èdè Switzerland), 1/15
Sún Mọ́ Ọlọ́run, 1/1, 2/1, 3/1, 4/1, 5/1, 6/1, 7/1, 8/1, 9/1, 10/1, 11/1, 12/1
Ṣé Ọlọ́run Ló Dá Èṣù? 3/1
Ta Ni Ọlọ́run? 2/1
JÉSÙ KRISTI
Bá A Ṣe Lè Máa Tọ Kristi Aṣáájú Pípé Náà Lẹ́yìn, 5/15
Gbólóhùn Náà “Ìwọ Fúnra Rẹ Wí I,” 6/1
Ibí tí Jésù Ti Wá; Bó Ṣe Gbé Ìgbé Ayé Rẹ̀; Ìdí Tó Fi Kú, 4/1
Ìgbẹ́jọ́, 4/1
Ǹjẹ́ Ó Ṣeé Ṣe Láti Sọ Ní Pàtó Iye Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Mèsáyà? 8/15
Ṣé Òótọ́ Ni Jésù Kú Lórí Àgbélébùú? 3/1
Ta Ni Jésù Kristi? 3/1
Wákàtí Tí Wọ́n Kan Jésù Kristi Mọ́gi, 11/15
Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN
“Agbo Ilé Késárì” (Flp 4:22), 3/1
Àjálù—Ṣé Ọlọ́run Ló Fi Ń Pọ́n Aráyé Lójú? 12/1
Àjọyọ̀ Ìyàsímímọ́ (Jo 10:22), 9/1
Àwọn Àpọ́sítélì Mú Ọ̀pá, Kí Wọ́n sì Wọ Sálúbàtà, 3/15
Àwọn Tó Ń Pààrọ̀ Owó Nínú Tẹ́ńpìlì, 10/1
Bárábà, 4/1
Báwo Làwọn Júù Ṣe Ń Mọ Iye Aago Tó Lù Nígbà Tí Ilẹ̀ Bá Ti Ṣú? 8/1
Báwo Ni Ipò Òṣì Ṣe Máa Dópin? 6/1
Bí Wọ́n Ṣe Ń Rí Owó Ná Sórí Àwọn Nǹkan Tí Wọ́n Ń Ṣe ní Tẹ́ńpìlì, 11/1
Ìdí Tí Sátánì Fi Lo Ejò, 1/1
Igi Ólífì Wúlò Gan-an, 10/1
Ìgbà Wo Ni Wọ́n Pa Jerúsálẹ́mù Run? 10/1, 11/1
“Ìhìn Rere Ìjọba” Náà, 3/1
Ilé Tí Nebukadinésárì Kọ́, 11/1
“Ilẹ̀ Kan Tí Ń Ṣàn fún Wàrà àti Oyin,” 3/1
Ìrètí Wà fún Àwọn Tó Ti Kú, 6/1
Ìrìbọmi fún Àwọn Ọmọ Ọwọ́, 10/1
Irú Àwọn Ẹ̀ṣẹ̀ Wo Ni Wọ́n Lè Torí Rẹ̀ Pààyàn bí Wọ́n Ṣe Pa Jésù? 4/1
Irú Ilé Wo Ló Ṣeé Ṣe Kí Ábúrámù Gbé? 1/1
Jéhù Jà fún Ìjọsìn Mímọ́, 11/15
Késárì, Kí Ló Túmọ̀ Sí? 7/1
Kí Lo Lè Fi Dá Ẹ̀sìn Tòótọ́ Mọ̀? 8/1
Kí Ló Mú Kí Mósè Bínú sí Àwọn Ọmọ Áárónì? (Le 10:16-20), 2/15
Kí Ni Amágẹ́dọ́nì? 9/1
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ìbálòpọ̀? 11/1
Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run? 7/1
Kí Nìdí Tó Fi Jẹ́ Pé Lẹ́bánónì Ni Sólómọ́nì Ti Kó Igi Gẹdú? 2/1
“Mo Ti Gbà Gbọ́” (Màtá), 4/1
‘Mú Àwọn Àkájọ Ìwé Wá àti Àwọn Ìwé Awọ,’ 6/15
Mú Kí Ìgbésí Ayé Rẹ Dára, 7/1
Ǹjẹ́ Ayé Máa Pa Run ní Ọdún 2012? 12/1
Ǹjẹ́ Ìwàláàyè Títí Láé Nínú Párádísè Máa Súni? 5/1
Ó Fara Da Ìjákulẹ̀ (Sámúẹ́lì), 1/1
Ó Gbèjà Àwọn Èèyàn Ọlọ́run (Ẹ́sítérì), 10/1
Ó Rí Ìtùnú Gbà Lọ́dọ̀ Ọlọ́run (Èlíjà), 7/1
Ojú Wo Ni Àwọn Aṣáájú Ẹ̀sìn Júù ní Ọjọ́ Jésù Fi Ń Wo Àwọn Gbáàtúù? 7/1
Omi Nígbà Ẹ̀ẹ̀rùn Lórílẹ̀-Èdè Ísírẹ́lì, 1/1
“Oríṣi Ohun Ọ̀gbìn Méje” Lára Ohun Ọ̀gbìn Ilẹ̀ Tí Ó Dára Náà, 9/1
Orúkọ Tí Wọ́n Fi Òǹtẹ̀ Lù Sára Amọ̀ Láyé Ìgbàanì, 5/1
Owó (ní àkókò tí wọ́n ń kọ Bíbélì), 5/1
“Òwú Aláwọ̀ Rírẹ̀dòdò Ti Kòkòrò Kókọ́sì,” 12/1
Ọgbà Édẹ́nì, 1/1
Ọkùnrin Kan Tí Ó Tẹ́ Ọkàn Jèhófà Lọ́rùn, 9/1
“Ọmọge, àní Àwọn Ọmọge” (Onw 2:8), 3/15
Pétérù Dé Sílé Ọkùnrin Kan Tó Jẹ́ Oníṣẹ́ Awọ, 6/1
Pípèéṣẹ́, 2/1
Ṣe Bó O Ti Mọ, 6/1
Ṣé Gbogbo Kristẹni Olóòótọ́ Ló Ń Lọ sí Ọ̀run? 6/1
Ṣé Ibi Tí Wọ́n Ti Ń Fi Iná Dáni Lóró Ni Gẹ̀hẹ́nà? 4/1
Ṣé Inú Ọkàn Ni Ìjọba Ọlọ́run Wà? 3/1
Ṣé Ò Ń Múra Sílẹ̀ fún Ọjọ́ Tó Ṣe Pàtàkì Jù Lọ Nínú Ọdún? 2/1
Ṣé Òótọ́ Ni Ábúráhámù Ní Ràkúnmí? 6/15
Ṣé Póòpù Ló “Rọ́pò Pétérù”? 8/180
Ṣíṣú Opó, 3/1
Ta Ló Lè Túmọ̀ Àsọtẹ́lẹ̀? 12/1
Ta Ló Ń Ṣàkóso Ayé? 9/1
Tẹ́tẹ́ Títa, 3/1
“Títàpá sí Ọ̀pá Kẹ́sẹ́” (Iṣe 26:14), 8/1
Wọ́n Rí Ará Ìlà Oòrùn Éṣíà Kan ní Ítálì Àtijọ́, 1/1