ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ March 2013

Àwọn àpilẹ̀kọ yìí ṣàlàyé ohun tí gbogbo àwa Kristẹni gbọ́dọ̀ ṣe ká lè máa ba eré ìje ìyè àìnípẹ̀kun náà nìṣó. Ó tún ṣàlàyé bá a ṣe lè mọ ọkàn wa àti bá a ṣe lè mọ Jèhófà Ọlọ́run wa.

‘Kò Sí Ohun Ìkọ̀sẹ̀’ fún Àwọn Tó Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà

Kí ló túmọ̀ sí pé kò sí ohun ìkọ̀sẹ̀ kankan fún àwọn tó nífẹ̀ẹ́ òfin Jèhófà? Kí ni kò ní jẹ́ kó o dẹ́kun sísá eré ìje ìyè?

Ǹjẹ́ Ó Wù Ẹ́ Láti Mọ Jèhófà?

Ọ̀rọ̀ wòlí ì Jeremáyà lè mú kó o ní ọkàn ìṣàpẹẹrẹ tó ń ṣiṣẹ́ dáadáa.

Ǹjẹ́ Ó Wù Ẹ́ Láti Mọ Jèhófà?

Ọ̀rọ̀ wòlí ì Jeremáyà lè mú kó o ní ọkàn ìṣàpẹẹrẹ tó ń ṣiṣẹ́ dáadáa.

Gba Ìtùnú, Kó O sì Tu Àwọn Mí ì Nínú

Kò sẹ́ni tí kì í ṣàìsàn. Àìsàn àwọn mí ì tiẹ̀ le koko gan-⁠an. Tá a bá dojú kọ irú ìṣòro bẹ́ẹ̀, kí la lè ṣe?

Jèhófà Ni Ibùgbé Wa

Bó tilẹ̀ jẹ́ pé inú ayé búburú là ń gbé, kí nìdí tó fi dá wa lójú pé Jèhófà máa dáàbò bo àwọn èèyàn rẹ̀?

Máa Gbé Orúkọ Ńlá Jèhófà Ga

Báwo ló ṣe máa ń rí lára rẹ tó o bá ń lo orúkọ Ọlọ́run? Kí ló túmọ̀ sí láti mọ orúkọ Ọlọ́run àti láti máa rìn ní orúkọ rẹ̀?

Ṣé Josephus Ló Kọ Ọ́ Lóòótọ́?

Ṣé òǹkọ̀wé ìtàn àwọn Júù tó ń jẹ́ Flavius Josephus ló kọ ìwé Testimonium Flavianum?

Má Ṣe Sọ̀rètí Nù!

Má ṣe ronú pé ẹnì kan ò lè wá sin Jèhófà. Kẹ́kọ̀ọ́ nípa àwọn tí kò sọ̀rètí nù àti ìdí tí wọn kò fi ṣe bẹ́ẹ̀.