ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ July 2014

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti September 1 sí 28, 2014 ló wà nínú ẹ̀dá yìí.

Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní Micronesia

Ó kéré tán ìpèníjà mẹ́ta làwọn tó ti òkèèrè wá sìn ní erékùṣù Pàsífí ìkì sábà máa ń ní. Àmọ́, kí ló ran àwọn àkéde yìí lọ́wọ́?

“Jèhófà Mọ Àwọn Tí Í Ṣe Tirẹ̀”

Báwo ni “ìpìlẹ̀” àti “èdìdì” tí ìwé 2 Tímótì 2:19, sọ ṣe mú ká mọ àwọn tó jẹ́ ti Jèhófà?

Àwọn èèyàn Jèhófà “Kọ Àìṣòdodo Sílẹ̀ Ní Àkọ̀tán”

Báwo ni gbólóhùn náà “kọ àìṣòdodo sílẹ̀ ní àkọ̀tán” ṣe bá ìṣẹ̀lẹ̀ tó wáyé lọ́jọ́ Mósè mu? Kí la rí kọ́ nínú àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ yẹn?

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Baba Kú, àmọ́ Baba Kù

Ka ìtàn ìgbésí ayé Gerrit Lösch, tó jẹ́ ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí.

“Ẹ̀yin Ni Ẹlẹ́rìí Mi”

Kí ni pípè tí wọ́n ń pè wá ní Ẹlẹ́rìí Jèhófà túmọ̀ sí?

“Ẹ Ó sì Jẹ́ Ẹlẹ́rìí Mi”

Kí nìdí tí Jésù fi sọ pé: “Ẹ ó sì jẹ́ ẹlẹ́rìí mi” dípò kó sọ pé wọ́n á jẹ́ ẹlẹ́rìí fún Jèhófà? Báwo la ṣe lè máa lo ìtara nìṣó nínú iṣẹ́ ìwàásù?