ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ April 2015

Awon apileko ta a maa kekoo lati June 1 sí June 28, 2015 lo wa ninu eda yii.

Eyin Alagba, Nje E Maa N Da Awon Mii Lekoo?

Mo nnkan meje ti awon alagba to mooyan ko maa n se.

Bi Awon Alagba Se N Ko Awon Mii Ki Won Le Tootun

Awon alagba le janfaani latinu ona ti Jesu gba da awon eeyan lekoo, nigba ti awon akekoo le fara we apeere Elisa.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Mo Gba Opo Ibukun Ni “Asiko Ti O Rogbo ati Ni Asiko Ti O Kun Fun Idaamu”

Itan igbesi aye Trophim Nsomba, to fara da inunibini to le koko ni orile-ede Malawi tori ohun to gba gbo, le je ko o tubo pinnu pe waa je oloooto.

Nje O Da E Loju Pe O Ni Ajose To Dan Moran Pelu Jehofa

Tawon meji ba n bara won soro deedee, ajose won a dan moran si i. Bawo ni eyi se le ran e lowo ninu ajose aarin iwo ati Olorun?

E Gbeke Le Jehofa Nigba Gbogbo!

O le bori okan pataki lara awon isoro ti ko ni je ko o ni ajose timotimo pelu Olorun.

Idi Ti Iyolegbe Fi Je Ipese Onifee

Bawo lo se je pe ohun kan to maa n ko edun bani gan-an je fun anfaani gbogbo wa?

Se Igi Ti Won Ge Lule Tun Le Hu Pa Da?

Idahun ibeere yii kan ireti to o ni fun ojo iwaju.