Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

◼ Táwọn èèyàn bá ń gbàdúrà pé kí Ìjọba Ọlọ́run dé, kí ni wọ́n ń fẹ́ gan-an?

OJU ÌWÉ 5.

◼ Báwo lo ṣe lè fi kọ́ra láti máa ronú kó o tó sọ̀rọ̀?

OJÚ ÌWÉ 10.

◼ Ṣé ipasẹ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ ẹfolúṣọ̀n ni Ọlọ́run fi dá àwa èèyàn?

OJÚ ÌWÉ 14.

◼ Ta ni Èlíjà, ẹ̀kọ́ wo la sì lè rí kọ́ lára rẹ̀ lónìí?

OJÚ ÌWÉ 18.

◼ Kí nìdí tá a fi lè mọ̀ dájú pé kì í ṣe ẹ̀yìn tí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tí Bíbélì sàsọtẹ́lẹ̀ wọn ṣẹlẹ̀ tán ni wọ́n tó kọ wọ́n?

OJÚ ÌWÉ 22.

◼ Kí nìdí tá a fi lè sọ pé Jèhófà Ọlọ́run ni Baba tó dára jù lọ?

OJÚ ÌWÉ 25.

◼ Ṣé lóòótọ́ làwọn awòràwọ̀ mú ẹ̀bùn wá fún Jésù lóru ọjọ́ tí wọ́n bí i?

OJÚ ÌWÉ 31.