Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
May 1, 2008
Kí Ni Ìṣẹ̀dá Ń Sọ Nípa Ọlọ́run?
NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
4 Ìṣẹ̀dá Ń Fi Ọgbọ́n Ọlọ́run Hàn
6 Àwọn Ìràwọ̀ Ń Fi Agbára Ọlọ́run Hàn
8 Ìfẹ́ Ìyá sí Ọmọ Ń Gbé Ìfẹ́ Ọlọ́run Yọ
13 Àjálù Ṣẹlẹ̀ ní Erékùṣù Solomon Islands
16 Ohun Tá A Kọ́ Lọ́dọ̀ Jésù—Nípa Ìjọba Ọlọ́run
18 Báwo Lo Ṣe Lè Mọ Bíbélì Tí Wọ́n Túmọ̀ Lọ́nà Tó Dára?
23 Abala Àwọn Ọ̀dọ́—Jésù Fi Iṣẹ́ Ìyanu Mú Àwọn Aláìsàn Lára Dá
24 Sún Mọ́ Ọlọ́run—Ẹni Tó Mọ Ìnira Wa
31 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀—Bá A Ṣe Lè Yanjú Ìṣòro Tó Bá Jẹ Yọ
OJÚ ÌWÉ 10
Bí A Ṣe Lè Tu Aláìsàn Tó Ń Retí Ikú Nínú
OJÚ ÌWÉ 25
[Àwọn àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
COVER: Snowflakes: SnowCrystals.com; beetle: Entom Pictures/Paul Eekhoff; page 32: Earth: Based on NASA photo