Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

◼ Ipa wo ni ṣíṣàṣàrò nípa ọ̀nà tí Ọlọ́run gbà dá àwọn ìràwọ̀ lè ní lórí rẹ? Wo ojú ewé 7.

◼ Ẹ̀kọ́ wo ni ìfẹ́ tí ìyá kan ní sí ọmọ rẹ̀ lè kọ́ ẹ nípa Ọlọ́run? Wo ojú ewé 9.

◼ Kí nìdí tó fi yẹ káwọn tọkọtaya máa fetí sí ara wọn, kí wọ́n sì máa fi hàn pé àwọn lóye ohun tó wà lọ́kàn ẹnì kejì wọn? Wo ojú ewé 11.

◼ Kí ni Ìjọba Ọlọ́run, kí ló sì máa gbé ṣe lórí ilẹ̀ ayé? Wo ojú ewé 16.

◼ Kí làwọn ohun pàtàkì táwọn aláìsàn tó ń retí ikú nílò? Wo ojú ewé 28.