Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
August 1, 2008
A Máa Tó Bọ́ Sínú Ìgbé Ayé Ìrọ̀rùn
NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
3 Ṣé Ayé Yìí Ti Fẹ́ Pa Rẹ́ Ni?
9 Sún Mọ́ Ọlọ́run—Ǹjẹ́ Ohunkóhun “Lè Yà Wá Kúrò Nínú Ìfẹ́ Ọlọ́run”?
13 Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Dúpẹ́ Oore?
18 Ṣé Ó Yẹ Kí Orúkọ Náà Jèhófà Wà Nínú Májẹ̀mú Tuntun?
24 Kọ́ Ọmọ Rẹ—Sámúẹ́lì Tẹra Mọ́ Ṣíṣe Ohun Tí Ó Tọ́
26 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
27 Bíbélì Máa Ń Sọni Dèèyàn Rere
Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀—Bá A Ṣe Lè Máa Bá Àwọn Ọmọ Tó Ṣẹ̀ṣẹ̀ Ń Bàlágà Sọ̀rọ̀
OJÚ ÌWÉ 10
Ohun Tá A Kọ́ Lọ́dọ̀ Jésù—Nípa Bó Ṣe Yẹ Ká Máa Hùwà Sáwọn Èèyàn
OJÚ ÌWÉ 16