Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ṣé Wàá Fẹ́ Ká Wá Ọ Wá?

Ṣé Wàá Fẹ́ Ká Wá Ọ Wá?

Ṣé Wàá Fẹ́ Ká Wá Ọ Wá?

Àní nínú ayé onídààmú yìí, ìmọ̀ pípéye látinú Bíbélì nípa Ọlọ́run, Ìjọba rẹ̀, àti ohun àgbàyanu tó fẹ́ ṣe fún aráyé lè fún ọ láyọ̀. Bó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i tàbí tó o fẹ́ kí ẹnì kan kàn sí ọ nílé láti kọ́ ẹ lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ́fẹ̀ẹ́, jọ̀wọ́ kọ̀wé sí Jehovah’s Witnesses, P.M.B. 1090, Benin City 300001, Edo State, Nigeria, tàbí sí àdírẹ́sì tó bá yẹ lára èyí tí a tò sí ojú ìwé 4.