Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

◼ Báwo la ṣe lè túbọ̀ láyọ̀, tí ìgbésí ayé wa sì túbọ̀ máa dáa tá a bá ń fara wé Jésù? Wo ojú ìwé 4.

◼ Kí nìdí tọ́rọ̀ ìmọ́tótó fi ṣe pàtàkì ju pé a ò fẹ́ kárùn lọ? Wo ojú ìwé 9.

◼ Báwo làwọn tó kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ ẹ̀sìn Kristẹni ṣe borí àwọn ìṣòro tí wọ́n ní nígbà tí wọ́n ń wàásù láwọn ibi táṣà àwọn Gíríìkì ti gbilẹ̀? Wo ojú ìwé 18.

◼ Ibo làwọn kan ti gba agbára ìwòsàn tí wọ́n ń pè ní iṣẹ́ ìyanu? Wo ojú ìwé 22.

◼ Kí lèrò àwọn méjì kan tó gba àmì ẹ̀yẹ Nobel nípa bí ìwé ìròyìn kan tí wọ́n fi 25-cent ṣètìlẹ́yìn fún ṣe dáhùn ìbéèrè nípa ibi tí àgbáálá ayé wa yìí ti ṣẹ̀ wá? Wo ojú ìwé 26.