Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
◼ Ṣé Jésù láwọn àbúrò? Wo ojú ìwé 6.
◼ Ṣáwọn òkú lè pa àwọn alààyè lára? Wo ojú ìwé 11.
◼ Ṣáwọn èèyàn lè tún ayé yìí ṣe? Wo ojú ìwé 18.
◼ Kí nìdí tí Jésù fi fọ ẹsẹ̀ àwọn àpọ́sítélì rẹ̀? Wo ojú ìwé 19.
◼ Ṣó yẹ ká máa retí pé kí Ọlọ́run dáhùn gbogbo àdúrà wa? Wo ojú ìwé 30.