Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

◼ Kí lorúkọ Ọlọ́run? Wo ojú ìwé 6.

◼ Tá ló ń ṣàkóso ayé yìí gan-an? Wo ojú ìwé 8.

◼ Tó o bá ti láwọn ọmọ, kí nìdí tó fi ṣe pàtàkì pé kó o wáyè láti máa fi gbọ́ tọkọ tàbí taya ẹ? Wo ojú ìwé 11.

◼ Kí ló ran obìnrin kan tó máa ń ṣe fàyàwọ́ dáyámọ́ǹdì lọ́wọ́ tó sì tún máa ń jí ẹrù ọ̀gá ẹ̀ láti di òṣìṣẹ́ tó ṣeé fọkàn tán? Wo ojú ìwé 26 àti 27.

◼ Kí nìdí táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà kì í fi í lo ère láti jọ́sìn Ọlọ́run? Wo ojú ìwé 30 àti 31.