Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

◼ Láwọn ọ̀nà wo ni Bíbélì gbà yàtọ̀ sí ọ̀pọ̀ ìwé olókìkí táwọn èèyàn máa ń wá ìtọ́sọ́nà nínú rẹ̀? Wo ojú ìwé 4.

◼ Kà nípa wàhálà táwọn tó tú Bíbélì sáwọn èdè ìgbàlódé ṣe àti ọgbọ́n tí wọ́n ta. Wo ojú ìwé 8.

◼ Ṣóòótọ́ ni pé Ọlọ́run kan náà ni gbogbo wa ń sìn? Wo ojú ìwé 12.

◼ Báwo ni iṣẹ́ ìwàásù ìhìn rere ṣe rí ní ilẹ̀ olótùútù, ìyẹn ní apá àríwá ilẹ̀ Sìbéríà? Wo ojú ìwé 24.

◼ Ibo lo ti lè rí ìtùnú àti ìrànlọ́wọ́ nígbà tó bá ń ṣe ẹ́ bíi pé kò sọ́nà àbáyọ, tí kò sì sí olùrànlọ́wọ́? Wo ojú ìwé 28.