Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
◼ Ṣé gbogbo ìsìn ló ń sinni lọ sọ́dọ̀ Ọlọ́run? Wo ojú ìwé 3.
◼ Kí ni Bíbélì kọ́ni nípa ìkọ̀sílẹ̀? Wo ojú ìwé 5.
◼ Ṣó yẹ kí ìsìn máa lọ́wọ́ sí ìṣèlú? Wo ojú ìwé 7 àti 8.
◼ Kí ló lè ran tọkọtaya lọ́wọ́ láti máa fohùn ṣọ̀kan lórí bí wọ́n ṣe fẹ́ náwó? Wo ojú ìwé 11 àti 12.
◼ Ṣé gbogbo èèyàn rere ló ń lọ sọ́run? Wo ojú ìwé 22 àti 23.
◼ Báwo làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe ń rówó tí wọ́n ń ná lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù tí wọ́n ń ṣe kárí ayé? Wo ojú ìwé 30.