Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
◼ Kà nípa ojútùú tó máa kárí ayé sí àwọn ìṣòro tó kárí ayé lóde òní. Wo ojú ìwé 5.
◼ Àwọn tó là á já níléèwé tí ẹnì kan ti yìnbọn pa àwọn èèyàn nílùú Winnenden lórílẹ̀-èdè Jámánì sọ bí wọ́n ṣe fara dà á lẹ́yìn ìpakúpa náà. Wo ojú ìwé 9.
◼ Ta ni Hẹ́rọ́dù Ọba tó fẹ́ pa Jésù nígbà tí Jésù ṣì wà ní ọmọ ọwọ́? Wo ojú ìwé 13.
◼ Kí lo mọ̀ nípa Ọdún Tuntun tí àwọn ará Ìlà Oòrùn Ayé máa ń ṣe? Wo ojú ìwé 20.
◼ Kà nípa orin kíkọ láyé ìgbà tí wọ́n ń kọ Bíbélì nípa ṣíṣàyẹ̀wò ìgbésí ayé Dáfídì Ọba. Wo ojú ìwé 26.
◼ Ṣé lóòótọ́ ni àwọn ọba tàbí amòye mẹ́ta wá jọ́sìn Jésù nígbà tó wà ní ibùjẹ ẹran? Wo ojú ìwé 31.
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 32]
Àwọn Ọmọ tí ebi ń pa: àjọ WHO/OXFAM