Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
Kẹ́kọ̀ọ́ nípa ohun tó jẹ́ èrò àwọn èèyàn nípa ẹ̀ṣẹ̀. WO OJÚ ÌWÉ 3 SÍ 10.
Kí ló lè ràn wá lọ́wọ́ láti jẹ́ olóòótọ́ bí ìwà àìṣòótọ́ ti gbilẹ̀ káàkiri? WO OJÚ ÌWÉ 11 SÍ 14.
Ṣe àwọn ìràwọ̀ ń darí ìgbésí ayé rẹ̀ lọ́nà kan? WO OJÚ ÌWÉ 18 SÍ 21.
Kí ni Ìwé Mímọ́ sọ nípa àwọn ẹ̀sìn ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ tí wọ́n ń jọ́sìn pa pọ̀? WO OJÚ ÌWÉ 27.
[Àwọn àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 32]
Àwọn ìràwọ̀: NASA, ESA, àti A. Nota (STScI); Àmúlùmálà ẹ̀sìn: REUTERS/Andreas Manolis