Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Kí lo lè ṣe láti fún ọ̀rẹ́ rẹ tó ń ṣàìsàn gan-an ní ìṣírí? WO OJÚ ÌWÉ 10 SÍ 13.

Ta ni Hánà, báwo sì ni ìgbàgbọ́ rẹ̀ ṣe ràn án lọ́wọ́ láti borí ìwà òǹrorò orogún rẹ̀? WO OJÚ ÌWÉ 14 SÍ 18.

Kí lo lè ṣe láti mú kí Bíbélì kíkà ṣe ọ́ láǹfààní? WO OJÚ ÌWÉ 19 SÍ 21.

Ǹjẹ́ Ọlọ́run ní ìbẹ̀rẹ̀? WO OJÚ ÌWÉ 28.

Kí ni Ọlọ́run ń wò nínú ọkàn wa? WO OJÚ ÌWÉ 29.