Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ṣé ayé máa pa run? WO OJÚ ÌWÉ 5.

Gẹ́gẹ́ bí Bíbélì ti sọ, kí ni Ọlọ́run máa fòpin sí? WO OJÚ ÌWÉ 5 SÍ 6.

Bí ọkọ tàbí aya rẹ bá múnú bí ẹ, kí ló máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti fọgbọ́n bá a sọ̀rọ̀? WO OJÚ ÌWÉ 12.

Kí ni Jésù sọ pé ó lè fúnni láyọ̀? WO OJÚ ÌWÉ 16.

Báwo ni ìdánilẹ́kọ̀ọ́ iṣẹ́ káfíńtà tí Jésù gbà ṣe nípa lórí ọ̀nà tó gbà kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́? WO OJÚ ÌWÉ 25 SÍ 26.

[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 32]

Fọ́tò U.S. National Archives