Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Kí ni Bíbélì sọ nípa bí gbogbo ìwà ibi ṣe máa dópin? WO OJÚ ÌWÉ 5.

Ǹjẹ́ ó ṣeé ṣe kí àwọn kan lára àwọn ohun tó o gbà gbọ́ jẹ́ ẹ̀tàn? WO OJÚ ÌWÉ 10.

Kí ló ti jẹ́ àbájáde ẹ̀kọ́ ìsìn Calvin láti ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta ọdún [500] tó ti wà? WO OJÚ ÌWÉ 18.

Ṣé ó pọn dandan kéèyàn jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀? WO OJÚ ÌWÉ 22.

Ibo ni Kéènì ọmọ Ádámù àti Éfà ti rí ìyàwó rẹ̀? WO OJÚ ÌWÉ 25.

[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 32]

Doré ló ṣe àwòrán yìí