Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ṣé ìmúṣẹ àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì ni iṣẹ́ ìwàásù tí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń ṣe?

WO OJÚ ÌWÉ 9.

Báwo ni ipò nǹkan ṣe máa rí lórí ilẹ̀ ayé nígbà tí Ìjọba Ọlọ́run bá ń ṣàkóso aráyé?

WO OJÚ ÌWÉ 10.

Kí ni tọkọtaya tó bímọ àkọ́bí lè ṣe bí ohùn wọn kò bá ṣọ̀kan lórí ọ̀nà tí wọ́n máa gbà tọ́ ọmọ?

WO OJÚ ÌWÉ 11.

Báwo ni ìwà ibi ṣe bẹ̀rẹ̀?

WO OJÚ ÌWÉ 16.

Kí nìdí tí ìjọba Rọ́ṣíà fi fòfin de àwọn kan lára àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

WO OJÚ ÌWÉ 18 SÍ 21.