Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
Àǹfààní wo làwọn ọmọdé máa jẹ bí wọ́n bá kọ́ wọn nípa Ọlọ́run?
WO OJÚ ÌWÉ 4 SÍ 6.
Kí ni tọkọtaya lè ṣe láti mú kí ọ̀wọ̀ tí wọ́n ń fún ara wọn máa pọ̀ sí i?
WO OJÚ ÌWÉ 11 SÍ 12.
Kí nìdí tí ọ̀pọ̀ ẹ̀sìn fi ń pe ara wọn ní Kristẹni?
WO OJÚ ÌWÉ 16.
Kí ló ran obìnrin kan lọ́wọ́ láti borí ìṣòro tó ní nígbà èwe rẹ̀ tó sì wá sún mọ́ Ọlọ́run?
WO OJÚ ÌWÉ 20 SÍ 21.
Ṣé Pétérù ni póòpù àkọ́kọ́?
WO OJÚ ÌWÉ 24 SÍ 25.