Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ṣé òótọ́ ni pé Bíbélì sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ọjọ́ ọ̀la?

WO OJÚ ÌWÉ 16 ATI 17.

Báwo ni ọmọbìnrin kan tí ìyà jẹ nígbà èwe rẹ̀ ṣe wá dẹni tí ayé rẹ̀ dára?

WO OJÚ ÌWÉ 19 SÍ 20.

Kí nìdí tí ọkùnrin olóòótọ́ náà Ábúráhámù fi gbìyànjú láti fi ọmọ rẹ̀ rúbọ?

WO OJÚ ÌWÉ 23.

Kí ni àpẹẹrẹ Ẹ́sítérì Ayaba tó wà nínú Bíbélì kọ́ wa nípa bá a ṣe lè nígboyà, sùúrù, àti bí èèyàn ṣe lè sọ̀rọ̀ lọ́nà tó ń yíni lọ́kàn pa dà?

WO OJÚ ÌWÉ 24 SÍ 29.