Ẹ̀kọ́ Bíbélì
Ẹ̀kọ́ Bíbélì
ỌMỌ ỌDÚN MẸ́TA ÀTI ÀWỌN TÍ KÒ TÓ BẸ́Ẹ̀
Ta ló dá ayé?
Ta ló dá òkun?
Ta ló dá ìwọ àti èmi?
Ta ló dá labalábá pẹ̀lú ìyẹ́ rẹ̀ aláràbarà?
Jèhófà Ọlọ́run ló dá ohun gbogbo Ìṣípayá 4:11
IṢẸ́ ÒBÍ
Kọ́ ọmọ rẹ:
Kí ni orúkọ Ọlọ́run?
Ibo ni Jèhófà ń gbé?
Kí ni Jèhófà dá?
Ní kí ọmọ rẹ tọ́ka sí:
Àwọn ìràwọ̀ Ojú ọ̀run Oòrùn
Ọkọ̀ ojú omi Ayé Ilé
Òkun Labalábá