Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
Ibo ni a ti lè rí ìsọfúnni tó ṣeé gbára lé nípa Jésù?
WO OJÚ ÌWÉ 3 sí 7.
Ǹjẹ́ Jèhófà tiẹ̀ bìkítà nípa àwọn tó ti sìn ín nígbà kan rí?
WO OJÚ ÌWÉ 10 sí 11.
Báwo ni ọ̀dọ́mọkùnrin kan tó ti ń wá ẹni tó máa fi ṣe bàbá ṣe dẹni tó fi Jèhófà ṣe bàbá?
WO OJÚ ÌWÉ 14 sí 15.
Kí ni a lè rí kọ́ lára Jósẹ́fù tó jẹ́ alágbàtọ́ Jésù?
WO OJÚ ÌWÉ 23 sí 28.