Ẹ̀kọ́ Bíbélì
Ẹ̀kọ́ Bíbélì
ỌMỌ ỌDÚN MẸ́TA ÀTI ÀWỌN TÍ KÒ TÓ BẸ́Ẹ̀
Wo àwọn ẹranko tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ ọkọ̀ Nóà.
Èwo ló máa ń ké mùúù, èwo ló sì máa ń gbó?
Gbogbo ẹranko, àwọn tó kéré àtàwọn tó tóbi, ọkọ̀ áàkì gba gbogbo wọn là. Jẹ́nẹ́sísì 7:7-10; 8:15-17
IṢẸ́ ÒBÍ
Ní kí ọmọ rẹ tọ́ka sí:
Ọkọ̀ Áàkì Béárì Ajá
Erin Àgùnfọn Kìnnìún
Ọ̀bọ Ẹlẹ́dẹ̀ Àgùntàn
Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ abilà Òṣùmàrè Igi
Ké bí àwọn ẹranko yìí ṣe ń ké:
Ajá Kìnnìún Ọ̀bọ
Ẹlẹ́dẹ̀ Àgùntàn