Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
Kí ni àwọn nǹkan tó mú kí Bíbélì yàtọ̀ sí gbogbo àwọn ìwé yòókù?
WO Ọ̀WỌ́ ÀPILẸ̀KỌ TÓ SỌ̀RỌ̀ LÓRÍ KÓKÓ YÌÍ NÍ OJÚ ÌWÉ 4 sí 9.
Tó o bá fẹ́ mọ̀ díẹ̀ nípa ìlú Tẹsalóníkà ìgbàanì àti iṣẹ́ ìwàásù tí Pọ́ọ̀lù ṣe níbẹ̀,
WO OJÚ ÌWÉ 18 sí 21.
Tí owó tó ń wọlé fúnni bá dín kù, kí ni èèyàn lè ṣe tí awọ á fi lè kájú ìlú?
Ǹjẹ́ àwọn nǹkan kan wà tí àwọn èèyàn máa ń sọ pé kò ṣeé ṣe, àmọ́ tó ṣeé ṣe?
WO OJÚ ÌWÉ 27 sí 29.
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 32]
Fọ́tò NASA