Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Kí nìdí tí Ọlọ́run fi fàyè gba kí ìyà máa jẹ àwa èèyàn?

WO OJÚ ÌWÉ 8 SÍ 9.

Kí nìdí tí aráyé fi nílò ìjọba kan tó máa ṣàkóso gbogbo ayé?

WO OJÚ ÌWÉ 16 SÍ 17.

Kí lo lè ṣe tí gbèsè ò fi ní máa gbé ọ lọ́kàn sókè?

WO OJÚ ÌWÉ 21.

Ṣé ẹni tó bá lóun ní ìgbàgbọ́ kàn ń tan ara rẹ̀ jẹ ni?

WO OJÚ ÌWÉ 23.