Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Kí lo rò pé ó yẹ kí àwọn èèyàn máa ṣe nígbà Kérésìmesì? Ǹjẹ́ ohun míì wà tó dára ju ọdún Kérésìmesì?

WO OJÚ ÌWÉ 3 SÍ 9.

Ǹjẹ́ o mọ ìdí tí Ọlọ́run fi rán Jésù wá sí ayé?

WO OJÚ ÌWÉ 16 SÍ 17.

Ǹjẹ́ o rò pé o ti gbé ayé nígbà kan rí ṣáájú èyí tí o ń gbé yìí? Àwọn kan gbà pé ṣe ni àwọn tún ayé wá, kí nìdí tí wọ́n fi rò bẹ́ẹ̀?

WO OJÚ ÌWÉ 18 SÍ 20.

Kí làwọn obìnrin máa ń lò láti fi gbé ẹwà wọn yọ ní ayé ìgbà tí wọ́n ń kọ Bíbélì?

WO OJÚ ÌWÉ 24 SÍ 26.