ILÉ ÌṢỌ́ January 2013 | Ǹjẹ́ Ó Yẹ Kéèyàn Máa Bẹ̀rù Òpin Ayé?

Gẹ́gẹ́ bí Bíbélì ṣe sọ, kí ni “òpin ayé”?

Sí Òǹkàwé Wa

Bẹ̀rẹ̀ látorí ẹ̀dà yìí, orí ìkànnì nìkan la ó ti máa gbé àwọn àpilẹ̀kọ kan nínú ìwé ìròyìn yìí jáde. Kà sí i nípa ìdí tá a fi ṣe ìyípadà yìí.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ǹjẹ́ Ó Yẹ Kéèyàn Máa Bẹ̀rù Òpin Ayé?

Ó lè yà ẹ́ lẹ́nu tó o bá gbọ́ ohun tí Bíbélì sọ nípa òpin ayé.

SÚN MỌ́ ỌLỌ́RUN

“O Ti . . . Ṣí Wọn Payá fún Àwọn Ìkókó”

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa bó o ṣe lè rí òtítọ́ nípa irú ẹni tí Ọlọ́run jẹ́ nínú Bíbélì.

BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ

“Ní Gbẹ̀yìn Gbẹ́yín Mo Ti Wá Ní Ojúlówó Òmìnira.”

Wo bí ẹ̀kọ́ Bíbélì ṣe mú kí ọ̀dọ́kùnrin kan jáwọ́ nínú sìgá mímu, lílo oògùn olóró àti ọtí àmujù.

TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN

“Bí Ó Tilẹ̀ Jẹ́ Pé Ó Kú, Ó Ń Sọ̀rọ̀ Síbẹ̀”

Wo ìdí pàtàkì mẹ́ta tí Ébẹ́lì fi ní ìgbàgbọ́ nínú Ẹlẹ́dàá tó jẹ́ onífẹ̀ẹ́.

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Kí ni orúkọ Ọlọ́run, kí sì nìdí tó fi yẹ ká máa lò ó?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Ṣọ́ra fún Owú!

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa bí Mósè ṣe hùwà nígbà tí àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ọkùnrin àti obìnrin ń jowú rẹ̀.