ILÉ ÌṢỌ́ March 2015 | Jesu Gba Wa—Lowo Ki Ni?
Se owo Esu lo ti gba wa, abi lowo ibinu Olorun, abi lowo nnkan mii?
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Idi Ti A Fi Nilo Igbala
Nje Olorun to nifee wa maa da wa pe ko maa wu wa lati gbe ile aye titi lae, ko tun wa mu ki o maa see se fun wa?
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Iku ati Ajinde Jesu—Anfaani To Se fun E
Bibeli so awon otito mefa to fi bi iku okunrin kan se maa mu iye wa fun opolopo.
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Iranti Iku Jesu ibi ta a ti maa se e ati igba ta a maa se e
Lodun 2015, ojo Friday, April 3, ni iranti iku Kristi bo si leyin ti oorun ba ti wo.
ÀWỌN ÒǸKÀWÉ WA BÉÈRÈ PÉ
Se O Ye Ki Awon Kristeni Maa Se Ayeye Odun Ajinde?
Ki lawon opitan so nipa ayeye to gbajumo yii?
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
Oju Jairo—Mu Ko Le Sin Olorun
Inu Jairo maa n dun, igbesi aye re si nitumo laika pe arun inu opolo to le ju lo n ba a finra.
Nje O Mo?
Anfaani wo ni apositeli Poolu ri ninu jije omo ibile Roomu? Bawo ni won se n sanwo ise fun awon oluso aguntan laye igba ti won n ko Bibeli?
Ebun To To Si Oba
Awon eroja yii le wopo lonii, amo won won to wura nigba ti won n ko Bibeli.
Ohun Ti Bibeli So
Awon wo lo ye ko je buredi ati waini nigba Iranti Iku Jesu?
Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì
Ǹjẹ́ Ó Yẹ Ká Máa Jọ́sìn Àwọn Ère?
Ǹjẹ́ Ọlọ́run fẹ́ ká máa lo àwọn ère nínú ìjọsìn wa?