Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

6 Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú: Ibo Ni Mo Ti Lè Rí Ìmọ̀ràn Tó Dáa Jù Lọ?

APÁ 1

Ọ̀RỌ̀ ỌKÙNRIN ÀTI OBÌNRIN

14 1 Ṣó Ti Yẹ Kí N Lẹ́ni Tí Mò Ń Fẹ́?

21 2 Kí Ló Burú Nínú Fífẹ́ra Sọ́nà ní Bòókẹ́lẹ́?

28 3 Ṣé Ẹni Tó Yẹ Kí N Fẹ́ Nìyí?

42 4 Ìgbà Wo Ló Dàṣejù?

48 5 Kí Nìdí Tí Kò Fi Yẹ Kí N Ní Ìbálòpọ̀ Kí N Tó Ṣègbéyàwó?

APÁ 2

ÌYÍPADÀ ARA

58 6 Kí Nìdí Tára Mi Fi Ń Yí Pa Dà?

67 7 Bí Mi Ò Bá Fẹ́ràn Bí Mo Ṣe Rí Ńkọ́?

74 8 Kí Nìdí Tí Mo Fi Ń Ṣàìsàn Tó Báyìí?

APÁ 3

YÍYAN Ọ̀RẸ́

86 9 Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Mi Ò Fi Ní Máa Dá Wà?

92 10 Kí Nìdí Táwọn Ọ̀rẹ́ Mi Fi Ń Ṣe Ohun Tó Ń Dùn Mí?

99 11 Kí Ló Burú Nínú Kéèyàn Máa Ṣọ̀rẹ́ Lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì?

105 12 Kí Ló Burú Nínú Kéèyàn Máa Sọ̀rọ̀ Ẹlòmíì Lẹ́yìn?

APÁ 4

ILÉÈWÉ ÀTÀWỌN OJÚGBÀ RẸ

114 13 Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Ṣe Dáadáa sí I Níléèwé?

121 14 Báwo Ni Mo Ṣe Lè Dáàbò Bo Ara Mi Níléèwé?

128 15 Báwo Ni Mi Ò Ṣe Ní Í Jẹ́ Káwọn Ojúgbà Mi Kó Ìwà Tí Ò Dáa Ràn Mí?

136 16 Ta Ló Yẹ Kí N Sọ fún bí Mo Bá Ń Yọ́ Ìwà Tí Kò Tọ́ Hù?

142 17 Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Yíyan Ọ̀rẹ́ Níléèwé?

APÁ 5

Ọ̀RÀN OWÓ

150 18 Báwo Ni Mo Ṣe Lè Lówó?

156 19 Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Ṣọ́ Owó Ná?

165 20 Báwọn Òbí Mi Ò Bá Lówó Ńkọ́?

APÁ 6

ÀWỌN ÒBÍ RẸ

174 21 Kí Ni Mo Lè Ṣe Táwọn Òbí Mi Bá Ń Rí sí Mi Ṣáá?

181 22 Òfin Yìí Ò Wa Pọ̀ Jù?

190 23 Bí Òbí Mi Bá Ń Mutí Lámujù Tó sì Ń Lòògùn Olóró Ńkọ́?

199 24 Kí Ni Kí Ń Ṣe Báwọn Òbí Mi Bá Ń Jà?

208 25 Báwo Ni Mo Ṣe Lè Láyọ̀ Bí Òbí Mi Bá Jẹ́ Anìkàntọ́mọ?

APÁ 7

BÍ NǸKAN ṢE Ń RÍ LÁRA Ẹ

218 26 Báwo Ni Mo Ṣe Lè Mú Ohun Tó Ń Ṣe Mí Mọ́ra?

225 27 Kí Ló Mú Kí N Máa Rò Pé Mi Ò Gbọ́dọ̀ Ṣàṣìṣe?

231 28 Báwo Ni Mo Ṣe Lè Sá fún Bíbá Ọkùnrin Tàbí Obìnrin Bíi Tèmi Lò Pọ̀?

237 29 Báwo Ni Mo Ṣe Lè Gbọ́kàn Mi Kúrò Lórí Ìbálòpọ̀?

APÁ 8

ERÉ ÌTURA

246 30 Ṣó Yẹ Kí N Máa Ṣeré Orí Kọ̀ǹpútà?

253 31 Báwo Ni Mi Ò Ṣe Ní Ki Àṣejù Bọ Orin Gbígbọ́?

263 32 Báwo Ni Mo Ṣe Lè Gbádùn Ara Mi?

273 33 Kí Nìdí Tí Kò Fi Yẹ Kí N Máa Wo Àwòrán Oníhòòhò?

APÁ 9

ÀJỌṢE RẸ PẸ̀LÚ ỌLỌ́RUN

282 34 Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí N Máa Fàwọn Ìlànà Bíbélì Ṣèwà Hù?

289 35 Báwo Ni Mo Ṣe Lè Di Ọ̀rẹ́ Ọlọ́run?

297 36 Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ṣàlàyé Ohun Tí Mo Gbà Gbọ́ Nípa Ọlọ́run?

304 37 Ṣó Yẹ Kí N Ṣèrìbọmi?

311 38 Kí Ni Màá Fayé Mi Ṣe?