Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ohun Tí Mo Rò—Àwọn Òbí Rẹ

Ohun Tí Mo Rò—Àwọn Òbí Rẹ

APÁ 6

Ohun Tí Mo Rò—Àwọn Òbí Rẹ

Kọ olórí ìṣòro tó o ní nínú ilé síbí yìí àti ìdí tí kò fi rọrùn láti kojú.

․․․․․

Lẹ́yìn tó o ti ka apá kẹfà ìwé yìí tán, báwo lo ṣe rò pé o lè yanjú ìṣòro tó o kọ sókè yìí?

․․․․․