Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ẹ̀kọ́ 3

Ẹ̀kọ́ 3

Ẹ̀kọ́ 3

1 Pétérù 3:8

Kúnlé gbọ́ pé ara ọ̀rẹ́ òun kò yá.

Ó sọ pé: “Mo mọ nǹkan tí màá ṣe.

Mo máa kọ lẹ́tà sí i kí ara rẹ̀ lè yá, màá sì mú un lọ fún un!”

Máa ṣe oore, inú ẹ̀yin méjèèjì yóò sì dùn!

IṢẸ́ ÒBÍ

Ka ẹsẹ Bíbélì yìí fún ọmọ rẹ:

1 Pétérù 3:8

Ní kí ọmọ rẹ tọ́ka sí:

Ilé Tábìlì Kúnlé

Oòrùn Ẹyẹ Igi

Bi ọmọ rẹ pé:

Ṣé o mọ ẹnì kan tí ara rẹ̀ kò yá?

Kí la lè ṣe láti ran ẹni yẹn lọ́wọ́?

[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 8]

[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 8]

[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 9]

[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 9]