Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ẹ̀kọ́ 4

Ẹ̀kọ́ 4

Ẹ̀kọ́ 4

Ìṣe 14:17

Òjò ń rọ̀.

Táyọ̀ ń sunkún pé:

“Mi ò lè jáde.

Kí ló dé tí òjò yìí ò dá?”

Ṣùgbọ́n lójijì!

Oòrùn yọ.

Òjò ti dá.

Inú Táyọ̀ dùn!

Ó sáré jáde, ó sì rí ohun kan tó yà á lẹ́nu.

Táyọ̀ sọ pé, “Mi ò mọ̀ pé òjò látọ̀dọ̀ Ọlọ́run ló ń mú kí òdòdó dàgbà!”

IṢẸ́ ÒBÍ

Ka ẹsẹ Bíbélì yìí fún ọmọ rẹ:

Ìṣe 14:17

Ní kí ọmọ rẹ tọ́ka sí:

Fèrèsé Ẹyẹ Táyọ̀

Igi Òdòdó

Fara balẹ̀ wá àwọn nǹkan yìí.

Kòkòrò Ọkọ̀ òfuurufú

Bi ọmọ rẹ pé:

Kí nìdí tí Jèhófà fi dá òjò?

[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 10]

[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 10]

[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 11]