Ẹ̀kọ́ 5
Ẹ̀kọ́ 5
Tí ọ̀rẹ́ rẹ kan bá fún ẹ ní ẹ̀bùn tàbí tó ṣe nǹkan tí inú rẹ dùn sí, o lè rẹ́rìn-ín sí i, o tiẹ̀ lè rẹ́rìn-ín sí i lẹ́ẹ̀mejì!
Nígbà gbogbo, nínú ohun gbogbo, máa rántí dúpẹ́ oore. Kó o máa sọ pé, “Ẹ ṣé!”
IṢẸ́ ÒBÍ
Ka ẹsẹ Bíbélì yìí fún ọmọ rẹ:
Ní kí ọmọ rẹ tọ́ka sí:
Ẹ̀bùn Ọkùnrin
Ilẹ̀kùn Oúnjẹ
Fara balẹ̀ wá àwọn nǹkan yìí.
Ápù Tẹlifóònù
Bi ọmọ rẹ pé:
Kí nìdí tó fi yẹ ká máa rántí sọ pé: “Ẹ ṣé”?
[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 12]
[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 13]
[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 13]
[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 13]