Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

“Máa Bá A Lọ Nínú Àwọn Ohun Tí O Ti Kọ́”

“Máa Bá A Lọ Nínú Àwọn Ohun Tí O Ti Kọ́”

“Máa Bá A Lọ Nínú Àwọn Ohun Tí O Ti Kọ́”

Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù ló kọ̀wé sí Tímótì ọ̀dọ́mọdé bẹ́ẹ̀. (2 Tímótì 3:14) Bó o ṣe ti ka ìwé yìí tán, ó ti mọ ọ̀pọ̀ ohun rere tí Ọlọ́run máa ṣe fún àwọn tó nífẹ̀ẹ́ rẹ̀. Àmọ́ ó ní láti máa bá a lọ láti tẹ̀ síwájú nípa tẹ̀mí. Inú àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà yóò dùn láti ràn ọ́ lọ́wọ́, ìyẹn bí ẹnikẹ́ni lára wa kò bá tíì máa wá sọ́dọ̀ rẹ títí di báyìí. Tó o bá fẹ́ àlàyé síwájú sí i tàbí tó o fẹ́ kí ọ̀kan lára àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa wá bá ọ kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ́fẹ̀ẹ́ nínú ilé rẹ, ṣáà ti kọ̀wé sí wa, kó o lo èyí tó bá yẹ lára àwọn àdírẹ́sì tó wà nísàlẹ̀ yìí.