Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwọn Ọ̀rẹ́ Àlàáfíà

Àwọn Ọ̀rẹ́ Àlàáfíà

LÚÙKÙ 10:6

Àárọ̀

  • 9:40 Ohùn Orin

  • 9:50 Orin 58 àti Àdúrà

  • 10:00 Ẹ Káàbọ̀, Ẹ̀yin Ọ̀rẹ́ Àlàáfíà!

  • 10:15 Ẹ Máa Wá Àwọn Ọ̀rẹ́ Àlàáfíà

  • 10:30 Jẹ́ Kí Ọmọ Aládé Àlàáfíà Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Bó O Ṣe Ń Wá Àwọn Ọ̀rẹ́ Àlàáfíà

  • 10:55 Orin 103 àti Ìfilọ̀

  • 11:05 Àwọn Ọ̀rẹ́ Àlàáfíà Ò Ní Kọ́ṣẹ́ Ogun Mọ́

  • 11:35 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi

  • 12:05 Orin 79

Ọ̀sán

  • 1:20 Ohùn Orin

  • 1:30 Orin 76

  • 1:35 Ìrírí

  • 1:45 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́

  • 2:15 Àpínsọ Àsọyé: Àwọn Ọ̀rẹ́ Àlàáfíà Máa Ń Ran Ara Wọn Lọ́wọ́

    • • “Ẹ Ṣí Ọkàn Yín Sílẹ̀ Pátápátá”

    • • Ran Àwọn Ọ̀dọ́ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ṣe Púpọ̀ Sí I

    • • Máa Bọlá Fáwọn Àgbàlagbà

  • 3:00 Orin 57 àti Ìfilọ̀

  • 3:10 Àwọn Ọ̀rẹ́ Àlàáfíà Máa Ń Fi Ire Ṣẹ́gun Ibi

  • 3:55 Orin 45 àti Àdúrà