Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí

Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí
  1. 1. Báwo la ṣe lè dá àwọn ọ̀rẹ́ àlàáfíà mọ̀? (Lúùkù 10:6)

  2. 2. Báwo la ṣe lè ran àwọn ọ̀rẹ́ àlàáfíà lọ́wọ́ kí wọ́n lè di ọ̀rẹ́ Ọlọ́run? (Mát. 10:11)

  3. 3. Báwo ni Ọmọ Aládé Àlàáfíà ṣe ń ràn wá lọ́wọ́ láti wá àwọn ọ̀rẹ́ àlàáfíà? (Àìsá. 9:​6, 7; Mát. 28:20)

  4. 4. Báwo la ṣe lè fi hàn pé ọ̀rẹ́ àlàáfíà ni wá? (Sm. 11:5; 2 Tím. 2:24; Jém. 3:​17, 18)

  5. 5. Báwo làwọn ọ̀rẹ́ àlàáfíà ṣe máa ń ran ara wọn lọ́wọ́? (2 Kọ́r. 6:13)

  6. 6. Báwo la ṣe lè “máa fi ire ṣẹ́gun ibi”? (Róòmù 12:​2, 6, 10, 18)

© 2022 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania

CA-brpgm23-YR