Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ìdílé Jèhófà Tó Wà Níṣọ̀kan

Ìdílé Jèhófà Tó Wà Níṣọ̀kan

ÉFÉSÙ 4:3

Àárọ̀

  • 9:30 Ohùn Orin

  • 9:40 Orin 85 àti Àdúrà

  • 9:50 Mọyì Àǹfààní Tó O Ní Láti Wà Nínú Ìdílé Jèhófà

  • 10:05 Àpínsọ Àsọyé: Wọ́n Mára Tu Àwọn Míì

    • • Élíhù

    • • Lìdíà

    • • Jésù

  • 11:05 Orin 100 àti Ìfilọ̀

  • 11:15 Máa Ran Àwọn Míì Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Di Ara Ìdílé Jèhófà

  • 11:30 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi

  • 12:00 Orin 135

Ọ̀sán

  • 1:10 Ohùn Orin

  • 1:20 Orin 132 àti Àdúrà

  • 1:30 Àsọyé fún Gbogbo Èèyàn: Ṣé Ayọ̀ àti Àlàáfíà Wà Nínú Ìdílé Rẹ?

  • 2:00 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́

  • 2:30 Orin 136 àti Ìfilọ̀

  • 2:40 Àpínsọ Àsọyé: Bó O Ṣe Lè Jẹ́ Kí Àlàáfíà Wà

    • • Máa Sọ “Ọ̀rọ̀ Tó Ń Gbéni Ró”

    • • “Máa Rìn Nínú Ìfẹ́”

    • • Má Ṣe Jẹ́ Káwọn Ọ̀tá Wa Dẹkùn Mú Ẹ

  • 3:40 ‘Máa Dúpẹ́ Nígbà Gbogbo’ Nítorí Ìdílé Wa Nípa Tẹ̀mí

  • 4:15 Orin 107 àti Àdúrà