Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí

Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí
  1. 1. Báwo la ṣe lè fi hàn pé a mọyì àǹfààní tá a ní láti wà nínú ìdílé Jèhófà? (Éfé. 4:3)

  2. 2. Báwo la ṣe lè mára tu àwọn míì, kí sì nìdí tó fi yẹ ká ṣe bẹ́ẹ̀? (Róòmù 15:7)

  3. 3. Báwo la ṣe lè ran ọ̀pọ̀ èèyàn lọ́wọ́ láti di ara ìdílé Jèhófà? (Éfé. 2:17; 6:15)

  4. 4. Báwo la ṣe lè jẹ́ kí àlàáfíà máa wà? (Éfé. 4:29; 5:​1, 2; 6:13)

  5. 5. Báwo la ṣe lè jẹ́ kí ìfẹ́ tá a ní fún ìdílé wa nípa tẹ̀mí jinlẹ̀ sí i? (Éfé. 1:​15, 16)

© 2022 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania

CA-copgm23-YR