Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ohun Tá A Fẹ́ Kí Àwọn Tó Wá sí Àpéjọ Yìí Mọ̀

Ohun Tá A Fẹ́ Kí Àwọn Tó Wá sí Àpéjọ Yìí Mọ̀

Ìrìbọmi Àwọn alàgbà ìjọ yín ti ṣètò tó bá àdúgbò yín mu kí àwọn tó bá kúnjú ìwọ̀n lè ṣèrìbọmi lẹ́yìn ìpàdé àárọ̀ Saturday.

Ọrẹ A túmọ̀ gbogbo àpéjọ yìí sí èdè tó lé ní ọgọ́rùn-ún márùn-ún (500). Ọrẹ tẹ́ ẹ̀ ń ṣe ń ṣètìlẹyìn fún iṣẹ́ tá à ń ṣe kárí ayé. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sórí Ìkànnì donate.pr418.com. A mọrírì gbogbo ọrẹ tẹ́ ẹ bá ṣe. Ìgbìmọ̀ Olùdarí sì fẹ́ fi àkókò yìí dúpẹ́ lọ́wọ́ yín fún bẹ́ ẹ ṣe ń fi owó yín ti Ìjọba Ọlọ́run lẹ́yìn.

Tí Ìgbìmọ̀ Olùdarí Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ṣètò

© 2022 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania