2017 Ìròyìn Ọdún Iṣẹ́ Ìsìn Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé
Ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn nípa iṣẹ́ ìwàásù àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà kárí ayé bẹ̀rẹ̀ láti September 2016 sí August 2017.
Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2017
Ìròyìn ọdọọdún yìí máa jẹ́ kó o rí bí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe sapá tó àti owó tí wọ́n ná sórí iṣẹ́ ìwàásù Ìjọba Ọlọ́run kárí ayé.
2017 Ìròyìn Orílẹ̀-èdè àti Ìpínlẹ̀
Ìròyìn yìí jẹ́ ká mọ iye wa, iye àwọn tó ṣe ìrìbọmi, iye àwọn tó wá sí Ìrántí Ikú Kristi àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.