Sunday
‘Ẹ DÚRÓ NÍNÚ ÌFẸ́ ỌLỌ́RUN’—JÚÙDÙ 21
ÒWÚRỌ̀
-
9:20 Fídíò Orin
-
9:30 Orin 106 àti Àdúrà
-
9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Má Gbàgbé Ohun Tí Ìfẹ́ Máa Ń Ṣe
-
Ìfẹ́ Máa Ń Ní Sùúrù àti Inú Rere (1 Kọ́ríńtì 13:4)
-
Ìfẹ́ Kì Í Jowú; Kì Í Fọ́nnu (1 Kọ́ríńtì 13:4)
-
Kì Í Gbéra Ga; Kì Í Hùwà Tí Kò Bójú Mu (1 Kọ́ríńtì 13:4, 5)
-
Kì Í Wá Ire Tirẹ̀ Nìkan; Kì Í Tètè Bínú (1 Kọ́ríńtì 13:5)
-
Kì Í Di Èèyàn Sínú; Kì Í Yọ̀ Lórí Àìṣòdodo (1 Kọ́ríńtì 13:5, 6)
-
Ó Máa Ń Yọ̀ Lórí Òtítọ́; Ó Máa Ń Mú Ohun Gbogbo Mọ́ra (1 Kọ́ríńtì 13:6, 7)
-
Ó Máa Ń Gba Ohun Gbogbo Gbọ́; Ó Máa Ń Retí Ohun Gbogbo (1 Kọ́ríńtì 13:7)
-
Ó Máa Ń Fara Da Ohun Gbogbo; Ìfẹ́ Kì Í Yẹ̀ Láé (1 Kọ́ríńtì 13:7, 8)
-
-
11:10 Orin 150 and àti Ìfilọ̀
-
11:20 ÀSỌYÉ FÚN GBOGBO ÈNÌYÀN: Ibo Lo Ti Lè Rí Ìfẹ́ Tòótọ́ Nínú Ayé Tó Kún fún Ìkórìíra Yìí? (Jòhánù 13:34, 35)
-
11:50 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́
-
12:20 Orin 1 àti Àkókò Ìsinmi
Ọ̀SÁN
-
1:35 Fídíò Orin
-
1:45 Orin 124
-
1:50 FÍÌMÙ: Ìtàn Jòsáyà: Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà; Kórìíra Ohun Búburú—Apá Kejì (2 Àwọn Ọba 22:3-20; 23:1-25; 2 Kíróníkà 34:3-33; 35:1-19)
-
2:20 Orin “Jẹ́ Kí N Ní Ìgboyà” àti Ìfilọ̀
-
2:30 “Fara Balẹ̀ Kíyè Sí Àwọn Ohun Tí Jèhófà Ṣe Nítorí Ìfẹ́ Rẹ̀ Tí Kì Í Yẹ̀” (Sáàmù 107:43; Éfésù 5:1, 2)
-
3:30 Orin Tuntun àti Àdúrà Ìparí