Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Jẹ́ Kí Ìgbàgbọ́ Ẹ Túbọ̀ Lágbára!

Jẹ́ Kí Ìgbàgbọ́ Ẹ Túbọ̀ Lágbára!

HÉBÉRÙ 10:39

ÒWÚRỌ̀

  • 9:40 Ohùn Orin

  • 9:50 Orin 119 àti Àdúrà

  • 10:00 Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Jẹ́ Kígbàgbọ́ Wa Lágbára Báyìí?

  • 10:15 Ṣé Ò Ń Rí “Ẹni Tí A Kò Lè Rí”?

  • 10:30 “Ìgbàgbọ́ Ń Tẹ̀ Lé Ohun Tí A Gbọ́”

  • 10:55 Orin 104 àti Ìfilọ̀

  • 11:05 “Èso ti Ẹ̀mí Ni . . .Ìgbàgbọ́”

  • 11:35 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi

  • 12:05 Orin 50

Ọ̀SÁN

  • 1:20 Ohùn Orin

  • 1:30 Orin 3

  • 1:35 Ìrírí

  • 1:45 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́

  • 2:15 Àpínsọ Àsọyé: Ran Àwọn Míì Lọ́wọ́ Kí Ìgbàgbọ́ Wọn Lè Lágbára

    • • Àwọn Ọ̀dọ́

    • • Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Rẹ

    • • Àwọn Tá A Jọ Ń Sin Jèhófà

  • 3:00 Orin 38 àti Ìfilọ̀

  • 3:10 “Tẹjú Mọ́ . . . Olórí Aṣojú àti Aláṣepé Ìgbàgbọ́ Wa”

  • 3:55 Orin 126 àti Àdúrà