Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí

Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí
  1. 1. Kí nìdí tó fi yẹ ká jẹ́ kígbàgbọ́ wa lágbára báyìí? (Héb. 10:39)

  2. 2. Báwo la ṣe lè “rí” Jèhófà bó tiẹ̀ jẹ́ pé a ò lè rí i lójúkojú? (Héb. 11:27)

  3. 3. Kí nìdí tó fi ṣe pàtàkì ká máa ṣàyẹ̀wò àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì? (Róòmù 10:17)

  4. 4. Báwo ni ẹ̀mí mímọ́ ṣe lè jẹ́ ká nígbàgbọ́? (Lúùkù 11:13; Gál. 5:22)

  5. 5. Báwo la ṣe lè ran àwọn míì lọ́wọ́ kí ìgbàgbọ́ wọn lè lágbára? (1 Tẹs. 2:7, 8)

  6. 6. Kí nìdí tó fi yẹ ká máa “tẹjú mọ́ . . . Olórí Aṣojú àti Aláṣepé ìgbàgbọ́ wa”? (Héb. 12:2, 3)