Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

“Ẹ Ní Ìgbàgbọ́”!

“Ẹ Ní Ìgbàgbọ́”!

JÒHÁNÙ 14:1

ÒWÚRỌ̀

  • 9:30 Ohùn Orin

  • 9:40 Orin 118 àti Àdúrà

  • 9:50 Báwo La Ṣe Lè “Ní Ìgbàgbọ́,” Kí sì Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Ní In?

  • 10:05 Àpínsọ Àsọyé: Máa Fara Wé Àwọn Tó Nígbàgbọ́

    • • Ísákì àti Rèbékà

    • • Ẹ́sítà

    • • Tímótì

  • 11:05 Orin 60 àti Ìfilọ̀

  • 11:15 ‘A Ní Ìgbàgbọ́, Torí Náà A Sọ̀rọ̀’

  • 11:30 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi

  • 12:00 Orin 52

Ọ̀SÁN

  • 1:10 Ohùn Orin

  • 1:20 Orin 9 àti Àdúrà

  • 1:30 Àsọyé fún Gbogbo Èèyàn: Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Ọlọ́run “Tí Kò Lè Parọ́”

  • 2:00 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́

  • 2:30 Orin 54 àti Ìfilọ̀

  • 2:40 Àpínsọ Àsọyé: Máa “Rìn Nípa Ìgbàgbọ́” Lójoojúmọ́

    • • “Má Ṣàníyàn Láé”

    • • ‘Máa Lo Àkókò Rẹ Lọ́nà Tó Dára Jù Lọ’

    • • Má Ṣe Jẹ́ “Apá Kan Ayé”

  • 3:40 “Jèhófà Mọ Àwọn Tó Jẹ́ Tirẹ̀”

  • 4:15 Orin 7 àti Àdúrà