Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí

Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí
  1. 1. Àǹfààní wo la máa rí tá a bá ní ìgbàgbọ́? (Jòh. 3:16)

  2. 2. Báwo la ṣe lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ ìgbàgbọ́ Ísákì àti Rèbékà, Ẹ́sítà pẹ̀lú Tímótì? (Oníw. 4:11, 12; Sm. 119:46; 2 Tím. 1:5)

  3. 3. Kí lá jẹ́ kó máa yá wa lára láti máa bá iṣẹ́ ìwàásù wa lọ bá a tiẹ̀ ń kojú ìṣòro? (2 Kọ́r. 4:13)

  4. 4. Báwo la ṣe lè máa “rìn nípa ìgbàgbọ́” lójoojúmọ́? (2 Kọ́r. 5:7)

  5. 5. Báwo la ṣe lè jẹ́ kí Jèhófà mọ̀ wá? (2 Tím. 2:19; Jém. 4:6; 2 Kọ́r. 13:5)