Saturday
“Ẹ máa jà fitafita torí ìgbàgbọ́”—Júùdù 3
ÀÁRỌ̀
-
9:20 Fídíò Orin
-
9:30 Orin 57 àti Àdúrà
-
9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Máa Rántí Pé Àwọn Aláìgbàgbọ́ Lè Di Onígbàgbọ́!
-
• Àwọn Ará Ìlú Nínéfè (Jónà 3:5)
-
• Àwọn Àbúrò Jésù (1 Kọ́ríńtì 15:7)
-
• Àwọn Gbajúmọ̀ (Fílípì 3:7, 8)
-
• Àwọn Tí Kò Ṣe Ẹ̀sìn Kankan (Róòmù 10:13-15; 1 Kọ́ríńtì 9:22)
-
-
10:30 Fi Ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! Ran Àwọn Èèyàn Lọ́wọ́ Kí Ìgbàgbọ́ Wọn Lè Lágbára (Jòhánù 17:3)
-
10:50 Orin 67 àti Ìfilọ̀
-
11:00 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Ìgbàgbọ́ Ń Mú Kí Wọ́n Ja Àjàṣẹ́gun
-
• Àwọn Tí Ọkọ Tàbí Aya Wọn Kì Í Ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà (Fílípì 3:17)
-
• Àwọn Tí Òbí Kan Ṣoṣo Tọ́ (2 Tímótì 1:5)
-
• Àwọn Tí Kò Ní Ọkọ Tàbí Aya (1 Kọ́ríńtì 12:25)
-
-
11:45 ÌRÌBỌMI: Ẹni Tó Bá Ń Ní Ìgbàgbọ́ Máa Ní Ìyè Àìnípẹ̀kun! (Mátíù 17:20; Jòhánù 3:16; Hébérù 11:6)
-
12:15 Orin 79 àti Àkókò Ìsinmi
Ọ̀SÁN
-
1:35 Fídíò Orin
-
1:45 Orin 24
-
1:50 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Bí Àwọn Ará Wa Ṣe Ń Fi Hàn Pé Àwọn Nígbàgbọ́ ní . . .
-
• Áfíríkà
-
• Amẹ́ríkà ti Àríwá
-
• Éṣíà
-
• Oceania
-
• Yúróòpù
-
• Amẹ́ríkà ti Gúúsù
-
-
2:15 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Jẹ́ Kí Ìgbàgbọ́ Mú Kó O Ṣe Púpọ̀ Sí I
-
• Kọ́ Èdè Míì (1 Kọ́ríńtì 16:9)
-
• Lọ Síbi Tí Àìní Pọ̀ Sí (Hébérù 11:8-10)
-
• Sapá Kó O Lè Lọ sí Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere (1 Kọ́ríńtì 4:17)
-
• Máa Ṣèrànwọ́ Níbi Iṣẹ́ Ìkọ́lé Ètò Ọlọ́run (Nehemáyà 1:2, 3; 2:5)
-
• Máa “Ya Ohun Kan Sọ́tọ̀” fún Iṣẹ́ Jèhófà (1 Kọ́ríńtì 16:2)
-
-
3:15 Orin 84 àti Ìfilọ̀
-
3:20 FÍDÍÒ: Dáníẹ́lì Nígbàgbọ́ Jálẹ̀ Ìgbésí Ayé Rẹ̀—Apá Kìíní (Dáníẹ́lì 1:1–2:49; 4:1-33)
-
4:20 “Ẹ Máa Jà Fitafita Torí Ìgbàgbọ́”! (Júùdù 3; Òwe 14:15; Róòmù 16:17)
-
4:55 Orin 38 àti Àdúrà Ìparí