Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí

Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí
  1. 1. Báwo la ṣe lè wọnú ìsinmi Ọlọ́run? (Jẹ́n. 2:1-3; Héb. 4:1, 11)

  2. 2. Báwo la ṣe lè jẹ́ kí agbára tí “ọ̀rọ̀ Ọlọ́run” ní hàn láyé wa? (1 Tẹs. 2:13; Héb. 4:12)

  3. 3. Kí nìdí tó fi yẹ ká jẹ́ kí Jèhófà máa tọ́ wa sọ́nà? (Àìsá. 26:7-9, 15, 20)

  4. 4. Kí ló yẹ ká ṣe tá a bá fẹ́ kí Jèhófà bù kún wa? (1 Pét. 1:13-15; 1 Jòh. 5:3)

  5. 5. Báwo la ṣe lè mú inú Jèhófà dùn? (Sm. 71:14, 15; Róòmù 12:2; 1 Pét. 4:10)

  6. 6. Kí lá jẹ́ ká túbọ̀ máa láyọ̀ bá a ṣe ń sin Jèhófà? (Jòh. 5:17)

© 2023 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania

CA-brpgm24-YR